ITAN IYANU TI KERESIMESI
Itan Keresimesi je itan iyanu ife alailegbe ti Olorun ni si omo eniyan. Jesu gan ni ere idi Keresimesi. Keresimesi je oro ti a mu ninu oro meji ti itumo re je Ajodun awon Kristieni. December 25, 1038AD ni a koko se ajoyo Keresimesi. Itan Keresimesi yi ko kan bere ni ile Isreali bi …